Lori oke o'un petele
NIbe l'agbe bi mi si o
NIbe l'agbe to mi d'agba oo
Ile ominira
EMI O F'ABEOKUTA SOGO
UN O DURO L'ORI Olumo
maayo l'oruko egba ooo
emi omo lisabi e e
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo;
Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo
Abeokuta ilu Egba
Nko ni gbagbe re
N o gbe o l'eke okan mi
Bii ilu odo oya
Emi o maayo l'ori Olumo
Emi o s'ogoo yi l'okan mi
Wipe ilu olokiki ooo
L'awa Egba n gbe
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo;
Maa yo, maa yo, maa yo o; l'Ori Olumo
Egba Anthem








Jubril Magbade,
General Secretary
Rotimi Oyekanmi,
Vice President
Seilat Ojulari,
Social Secretary
Omowunmi Seidu, Financial Secretary
Executive Members
Our strength lies in our individuality...
Tomiwa Sowole, Treasurer


Olusegun Adepegba, President


Our Mission Statement




Gbenga Shobowale,
PRO
Oloyede Oladapo,
Governor General




Zac Shodiya,
Patron
Chief/Mrs. Sotomi-Kuti,
Matron
Join us in making a difference in the lives of those in need.
Dedicated to helping less privileged with water, education fund, and volunteering services.
